Skip to product information
1 of 1

Independently Published

Jesu Ak?Ni Mi/Jesus My Hero: Yoruba Bilingual Translation

Jesu Ak?Ni Mi/Jesus My Hero: Yoruba Bilingual Translation

ISBN-13: 9781091393264
Regular price $13.54
Regular price Sale price $13.54
Sale Sold out
L?yin Halloween ni ?dun to k?ja, ?m? mi Ivan, ?m? ?dun meji ?aa deede b??r? si ni b?ru ?mi ad?rubaniyan nigbati o ba wa ninu okunkun. O b??r? si ni isoro lati sun laal?. Yio ji ni ?p?l?p? igba- p?lu omi ?kun - yio maa wipe: "Ad?rubaniyan ...?ru n bami..."Nitori eleyi, emi ati ?k? mi gbiyanju ni gbogbo ?na lati ?alaye nipa Jesus Kiristi fun n sugb?n ko ye e. Nitorib?, mo pinnu lati ?e iwe aw?n ?m?de, eyi ti o mu u r?run lati m? ?niti Jesu j?. Iwe naa ni a pe ni "Jesu Ak?ni Mi" nitoripe, O ku lori agbelebu fun ??? wa ti O si GBA WA LA l?w? iparun ayeraye. Oun ni ak?ni didara jul?! Iwe naa j? abala marun (oju ewe m?wa) nitorib? o se e ka ni alaal? fun aw?n ?m? wa. Ati wipe nigbati w?n ba dagba to o, w?n le e ka fun ra a w?n! Jesu Ak?ni Mi s?r? nipa agbara Jesu lori ??ru, aisan, ijaya ati aw?n iwulo ojoojum? wa (igbesi aye ile-iwe) - eyiti o niise p?lu aw?n ?d? wa (ati aw?n ti o dagba di?) ni ode oni ati ?j? iwaju.After Halloween last year, my 2-year-old son, Ivan, developed a sudden fear of monsters and being in the dark. He started struggling to sleep. He would often wake up - in tears - saying: "monsters... I'm scared..." Following that, my husband and I regularly try to explain who Jesus Christ is to him but he doesn't understand. So I decided to make a children book, that simplifies who Jesus is. The book is called "Jesus My Hero" because he died on the cross for our sins and SAVED us from eternal damnation. He is the ultimate superhero! The book is only 5 spreads (10 pages) long, so it can be read every night to our little ones. And when they're old enough, they can read it for themselves! Jesus My Hero addresses Jesus' power in the matters of fear, sickness, anxiety and general everyday needs (i.e school life) - all which affect our young (and older) children in this day and age.


  • • Author: Michael Williams
  • • Publisher: Independently Published
  • • Publication Date: Mar 30, 2019
  • • Number of Pages: 25 pages
  • • Language: English
  • • Binding: Paperback
  • • ISBN-10: 1091393265
  • • ISBN-13: 9781091393264
View full details